Kronika Keji 26:19 BM

19 Inú bí Usaya nítorí pé àwo turari ti wà lọ́wọ́ rẹ̀ tí ó fẹ́ fi sun turari. Níbi tí ó ti ń bínú sí àwọn alufaa, àrùn ẹ̀tẹ̀ yọ níwájú rẹ̀, lójú àwọn alufaa ninu ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Keji 26

Wo Kronika Keji 26:19 ni o tọ