Kronika Keji 26:3 BM

3 Ọmọ ọdún mẹrindinlogun ni Usaya nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mejilelaadọta. Jekolaya, ará Jerusalẹmu ni ìyá rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 26

Wo Kronika Keji 26:3 ni o tọ