Kronika Keji 28:14 BM

14 Nítorí náà, àwọn ọmọ ogun náà dá àwọn tí wọ́n kó lẹ́rú ati ẹrù tí wọn ń kó bọ̀ sílẹ̀ níwájú àwọn ìjòyè ati gbogbo ìjọ eniyan Israẹli.

Ka pipe ipin Kronika Keji 28

Wo Kronika Keji 28:14 ni o tọ