Kronika Keji 29:19 BM

19 Gbogbo àwọn ohun èlò tí Ahasi ọba ti patì nígbà tí ó ṣe aiṣododo ni a ti tọ́jú, tí a sì ti yà sí mímọ́. A ti kó gbogbo wọn siwaju pẹpẹ OLUWA.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 29

Wo Kronika Keji 29:19 ni o tọ