Kronika Keji 3:15 BM

15 Ó ṣe òpó meji sí iwájú ilé náà, ọ̀kọ̀ọ̀kan rẹ̀ ga ní igbọnwọ marundinlogoji (mita 15). Ọpọ́n orí ọ̀kọ̀ọ̀kan ga ní ìwọ̀n igbọnwọ marun-un (mita 2¼).

Ka pipe ipin Kronika Keji 3

Wo Kronika Keji 3:15 ni o tọ