Kronika Keji 3:17 BM

17 Ó gbé àwọn òpó náà kalẹ̀ níwájú tẹmpili, ọ̀kan ní ìhà àríwá, wọ́n ń pè é ní Jakini, ekeji ní ìhà gúsù, wọ́n ń pè é ní Boasi.

Ka pipe ipin Kronika Keji 3

Wo Kronika Keji 3:17 ni o tọ