Kronika Keji 30:12 BM

12 Ọlọrun lọ́wọ́ sí ohun tí àwọn ará Juda ń ṣe, ó fi sí wọn ní ọkàn láti mú àṣẹ tí ọba ati àwọn olórí pa fún wọn ṣẹ, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Keji 30

Wo Kronika Keji 30:12 ni o tọ