Kronika Keji 30:17 BM

17 Àwọn tí wọn kò tíì ya ara wọn sí mímọ́ pọ̀ níbi àpéjọ náà, nítorí náà, àwọn ọmọ Lefi bá wọn pa ẹran wọn kí àwọn ẹran náà lè jẹ́ mímọ́ fún OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Keji 30

Wo Kronika Keji 30:17 ni o tọ