Kronika Keji 30:27 BM

27 Àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi dìde, wọ́n súre fún àwọn eniyan; OLUWA gbọ́ ohùn wọn, adura wọn sì gòkè lọ sí ibùgbé mímọ́ rẹ̀ lọ́run.

Ka pipe ipin Kronika Keji 30

Wo Kronika Keji 30:27 ni o tọ