Kronika Keji 30:3 BM

3 Ṣugbọn wọn kò lè ṣe é ní àkókò rẹ̀ nítorí àwọn alufaa tí wọ́n ti ya ara wọn sí mímọ́ kò tíì pọ̀ tó, àwọn eniyan kò sì tíì péjọ sí Jerusalẹmu tán.

Ka pipe ipin Kronika Keji 30

Wo Kronika Keji 30:3 ni o tọ