Kronika Keji 32:19 BM

19 Wọ́n sọ̀rọ̀ Ọlọrun Jerusalẹmu gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn oriṣa àtọwọ́dá tí àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn ń bọ.

Ka pipe ipin Kronika Keji 32

Wo Kronika Keji 32:19 ni o tọ