Kronika Keji 32:22 BM

22 Bẹ́ẹ̀ ni OLUWA ṣe gba Hesekaya ati àwọn ará Jerusalẹmu sílẹ̀ lọ́wọ́ Senakeribu, ọba Asiria, ati gbogbo àwọn ọ̀tá Hesekaya, ó sì fún un ní alaafia.

Ka pipe ipin Kronika Keji 32

Wo Kronika Keji 32:22 ni o tọ