Kronika Keji 32:25 BM

25 ṣugbọn Hesekaya ṣe ìgbéraga, kò fi ẹ̀mí ìmoore hàn fún ohun tí Ọlọrun ṣe fún un. Nítorí náà, inú bí OLUWA sí àtòun ati Juda ati Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Kronika Keji 32

Wo Kronika Keji 32:25 ni o tọ