Kronika Keji 32:27 BM

27 Hesekaya ní ọpọlọpọ ọrọ̀ ati ọlá. Ó kọ́ ilé ìṣúra tí ó kó fadaka, ati wúrà, ati òkúta olówó iyebíye, ati turari sí, ati apata ati gbogbo nǹkan olówó iyebíye.

Ka pipe ipin Kronika Keji 32

Wo Kronika Keji 32:27 ni o tọ