29 Bákan náà, ó kọ́ ọpọlọpọ ìlú fún ara rẹ̀, ó sì ní agbo ẹran lọpọlọpọ, nítorí Ọlọrun ti fún un ní ọrọ̀ lọpọlọpọ.
Ka pipe ipin Kronika Keji 32
Wo Kronika Keji 32:29 ni o tọ