Kronika Keji 32:9 BM

9 Lẹ́yìn èyí, nígbà tí Senakeribu ati àwọn ogun rẹ̀ gbógun ti Lakiṣi, ó ranṣẹ sí Hesekaya ọba Juda ati àwọn ará Juda tí wọ́n wà ní Jerusalẹmu pé,

Ka pipe ipin Kronika Keji 32

Wo Kronika Keji 32:9 ni o tọ