12 Nígbà tí ó wà ninu ìpọ́njú ó wá ojurere OLUWA Ọlọrun, ó sì rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ patapata níwájú Ọlọrun àwọn baba rẹ̀.
Ka pipe ipin Kronika Keji 33
Wo Kronika Keji 33:12 ni o tọ