Kronika Keji 33:17 BM

17 Sibẹsibẹ àwọn eniyan ṣì ń rúbọ ní àwọn ibi ìrúbọ, ṣugbọn OLUWA Ọlọrun wọn ni wọ́n ń rúbọ sí.

Ka pipe ipin Kronika Keji 33

Wo Kronika Keji 33:17 ni o tọ