22 Ó ṣe nǹkan burúkú lójú OLUWA, bíi Manase, baba rẹ̀, ó rúbọ sí gbogbo oriṣa tí baba rẹ̀ ṣe, ó sì ń bọ wọ́n.
Ka pipe ipin Kronika Keji 33
Wo Kronika Keji 33:22 ni o tọ