Kronika Keji 34:32 BM

32 Lẹ́yìn náà, ó ní kí àwọn ẹ̀yà Bẹnjamini ati àwọn ará Jerusalẹmu bá OLUWA dá majẹmu kí wọ́n sì pa á mọ́. Àwọn ará Jerusalẹmu sì pa majẹmu OLUWA Ọlọrun àwọn baba wọn mọ́.

Ka pipe ipin Kronika Keji 34

Wo Kronika Keji 34:32 ni o tọ