Kronika Keji 35:17 BM

17 Àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n wá ṣe àsè Àjọ Ìrékọjá, wọ́n sì ṣe Àjọ Àìwúkàrà fún ọjọ́ meje.

Ka pipe ipin Kronika Keji 35

Wo Kronika Keji 35:17 ni o tọ