2 Ó yan àwọn alufaa sí ipò wọn, ó sì gbà wọ́n níyànjú kí wọ́n ṣe iṣẹ́ wọn ninu ilé OLUWA.
Ka pipe ipin Kronika Keji 35
Wo Kronika Keji 35:2 ni o tọ