20 Nígbà tí ó yá lẹ́yìn tí Josaya ti ṣe ètò inú tẹmpili tán, Neko, ọba Ijipti wá jagun ní Kakemiṣi, ní odò Yufurate. Josaya sì digun lọ bá a jà.
Ka pipe ipin Kronika Keji 35
Wo Kronika Keji 35:20 ni o tọ