Kronika Keji 35:25 BM

25 Wolii Jeremaya kọ orin arò fún Josaya ọba. Ó ti di àṣà ní Israẹli fún àwọn akọrin, lọkunrin ati lobinrin láti máa mẹ́nu ba Josaya nígbàkúùgbà tí wọ́n bá ń kọrin arò.

Ka pipe ipin Kronika Keji 35

Wo Kronika Keji 35:25 ni o tọ