Kronika Keji 36:21 BM

21 kí ohun tí OLUWA ti sọ láti ẹnu wolii Jeremaya lè ṣẹ, pé, “Ilẹ̀ náà yóo di ahoro fún aadọrin ọdún kí ó lè ní gbogbo ìsinmi tí ó yẹ kí ó ti ní, ṣugbọn tí kò ní.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 36

Wo Kronika Keji 36:21 ni o tọ