Kronika Keji 4:11 BM

11 Huramu mọ ìkòkò, ó rọ ọkọ́, ó sì ṣe àwọn àwo kòtò. Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe parí iṣẹ́ tí ó ṣe sinu ilé Ọlọrun fún Solomoni ọba.

Ka pipe ipin Kronika Keji 4

Wo Kronika Keji 4:11 ni o tọ