Kronika Keji 4:9 BM

9 Ó kọ́ gbọ̀ngàn kan fún àwọn alufaa, ati òmíràn tí ó tóbi, ó ṣe ìlẹ̀kùn sí wọn, ó sì yọ́ idẹ bo àwọn ìlẹ̀kùn náà.

Ka pipe ipin Kronika Keji 4

Wo Kronika Keji 4:9 ni o tọ