Kronika Keji 5:10 BM

10 Ohun kan ṣoṣo tí ó wà ninu àpótí náà ni tabili meji tí Mose kó sibẹ ní òkè Horebu, níbi tí Ọlọrun ti bá àwọn ọmọ Israẹli dá majẹmu nígbà tí wọ́n jáde kúrò ní Ijipti.

Ka pipe ipin Kronika Keji 5

Wo Kronika Keji 5:10 ni o tọ