6 Solomoni ọba ati gbogbo ìjọ Israẹli dúró níwájú àpótí majẹmu, wọ́n ń fi ọpọlọpọ aguntan ati ọpọlọpọ mààlúù tí kò níye rúbọ.
Ka pipe ipin Kronika Keji 5
Wo Kronika Keji 5:6 ni o tọ