Kronika Keji 6:19 BM

19 Sibẹsibẹ, jọ̀wọ́ fetí sí adura ati ẹ̀bẹ̀ èmi iranṣẹ rẹ. OLUWA Ọlọrun mi, gbọ́ igbe èmi iranṣẹ rẹ, ati adura tí mò ń gbà níwájú rẹ.

Ka pipe ipin Kronika Keji 6

Wo Kronika Keji 6:19 ni o tọ