Kronika Keji 6:4 BM

4 Lẹ́yìn náà, ó ní, “Ẹni ìyìn ni OLUWA Ọlọrun Israẹli, tí ó mú ohun gbogbo tí ó wí fún Dafidi, baba mi, ṣẹ fúnrarẹ̀, nítorí ó wí pé,

Ka pipe ipin Kronika Keji 6

Wo Kronika Keji 6:4 ni o tọ