Kronika Keji 7:10 BM

10 Ní ọjọ́ kẹtalelogun oṣù keje, Solomoni ní kí àwọn eniyan máa pada lọ sílé wọn. Inú wọn dùn nítorí ohun rere tí OLUWA ṣe fún Dafidi, ati Solomoni ati gbogbo Israẹli.

Ka pipe ipin Kronika Keji 7

Wo Kronika Keji 7:10 ni o tọ