Kronika Keji 8:16 BM

16 Bẹ́ẹ̀ ni Solomoni ṣe ṣe gbogbo iṣẹ́ tí ó ṣe láti ìgbà tí ó ti fi ìpìlẹ̀ ilé OLUWA lélẹ̀ títí di ìgbà tí ó parí iṣẹ́ náà patapata.

Ka pipe ipin Kronika Keji 8

Wo Kronika Keji 8:16 ni o tọ