Kronika Keji 8:5 BM

5 Ó kọ́ ìlú Beti Horoni ti òkè ati Beti Horoni ti ìsàlẹ̀. Wọ́n jẹ́ ìlú olódi, wọ́n ní ìlẹ̀kùn ati ọ̀pá ìdábùú ìlẹ̀kùn,

Ka pipe ipin Kronika Keji 8

Wo Kronika Keji 8:5 ni o tọ