Kronika Keji 8:7 BM

7 Gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n kù ní ilẹ̀ náà lára àwọn ará Hiti, ati àwọn ará Amori, àwọn ará Perisi, àwọn ará Hifi ati àwọn ará Jebusi, tí wọn kì í ṣe ọmọ Israẹli,

Ka pipe ipin Kronika Keji 8

Wo Kronika Keji 8:7 ni o tọ