10 Àwọn iranṣẹ Huramu ati àwọn iranṣẹ Solomoni tí wọ́n mú wúrà wá láti Ofiri, tún mú igi aligumu ati àwọn òkúta olówó iyebíye wá pẹlu.
Ka pipe ipin Kronika Keji 9
Wo Kronika Keji 9:10 ni o tọ