Kronika Keji 9:20 BM

20 Wúrà ni wọ́n fi ṣe gbogbo ife Solomoni, ati gbogbo ohun èlò tí ó wà ní ilé Igbó Lẹbanoni. Fadaka kò jámọ́ nǹkankan ní àkókò ìjọba Solomoni.

Ka pipe ipin Kronika Keji 9

Wo Kronika Keji 9:20 ni o tọ