27 Ní àkókò tirẹ̀, ó mú kí fadaka pọ̀ bí òkúta ní Jerusalẹmu, igi kedari sì pọ̀ bíi igi sikamore tí ó wà ní ẹsẹ̀ òkè Juda.
Ka pipe ipin Kronika Keji 9
Wo Kronika Keji 9:27 ni o tọ