Gẹn 14:7 YCE

7 Nwọn si pada, nwọn si wá si Enmiṣpati, eyini ni Kadeṣi, nwọn si kọlu gbogbo oko awọn ara Amaleki, ati awọn ara Amori ti o tẹdo ni Hasesontamari pẹlu.

Ka pipe ipin Gẹn 14

Wo Gẹn 14:7 ni o tọ