8 Ọba Sodomu si jade, ati ọba Gomorra, ati ọba Adma, ati ọba Seboimu, ati ọba Bela, (eyini ni Soari;) nwọn si tẹgun si ara wọn li afonifoji Siddimu;
Ka pipe ipin Gẹn 14
Wo Gẹn 14:8 ni o tọ