Gẹn 19:28 YCE

28 O si wò ìha Sodomu on Gomorra, ati ìha gbogbo ilẹ àgbegbe wọnni, o si wò o, si kiyesi i, ẽfin ilẹ na rú soke bi ẽfin ileru.

Ka pipe ipin Gẹn 19

Wo Gẹn 19:28 ni o tọ