Gẹn 19:29 YCE

29 O si ṣe nigbati Ọlọrun run ilu àgbegbe wọnni ni Ọlọrun ranti Abrahamu, o si rán Loti jade kuro lãrin iparun na, nigbati o run ilu wọnni ninu eyiti Loti gbé ti joko.

Ka pipe ipin Gẹn 19

Wo Gẹn 19:29 ni o tọ