Gẹn 23:19 YCE

19 Lẹhin eyi li Abrahamu sin Sara, aya rẹ̀, ninu ihò oko Makpela, niwaju Mamre: eyi nã ni Hebroni ni ilẹ Kenaani.

Ka pipe ipin Gẹn 23

Wo Gẹn 23:19 ni o tọ