20 Ati oko na, ati ihò ti o wà nibẹ̀, li a ṣe daju fun Abrahamu, ni ilẹ isinku, lati ọwọ́ awọn ọmọ Heti wá.
Ka pipe ipin Gẹn 23
Wo Gẹn 23:20 ni o tọ