1 ABRAHAMU si gbó, o si pọ̀ li ọjọ́: OLUWA si ti busi i fun Abrahamu li ohun gbogbo.
Ka pipe ipin Gẹn 24
Wo Gẹn 24:1 ni o tọ