Gẹn 24:17 YCE

17 Iranṣẹ na si sure lọ ipade rẹ̀, o si wipe, Emi bẹ̀ ọ, jẹ ki nmu omi diẹ ninu ladugbo rẹ.

Ka pipe ipin Gẹn 24

Wo Gẹn 24:17 ni o tọ