18 O si dahùn pe, Mu, oluwa mi: o si yara, o sọ̀ ladugbo rẹ̀ ka ọwọ́, o si fun u mu.
Ka pipe ipin Gẹn 24
Wo Gẹn 24:18 ni o tọ