51 Wò o, Rebeka niyi niwaju rẹ, mu u, ki o si ma lọ, ki on ki o si ma ṣe aya ọmọ oluwa rẹ, bi OLUWA ti wi.
Ka pipe ipin Gẹn 24
Wo Gẹn 24:51 ni o tọ