63 Isaaki si jade lọ ṣe àṣaro li oko li aṣalẹ: o si gbé oju rẹ̀ soke, o si ri i, si kiyesi i, awọn ibakasiẹ mbọ̀wá.
Ka pipe ipin Gẹn 24
Wo Gẹn 24:63 ni o tọ