Gẹn 43:27 YCE

27 On si bère alafia wọn, o si wipe, Alafia ki baba nyin wà, arugbo na ti ẹnyin wi? o wà lãye sibẹ̀?

Ka pipe ipin Gẹn 43

Wo Gẹn 43:27 ni o tọ